256 views

AUDIO: Tope Alabi – Mimo L'Oluwa [Lyrics + Mp3 Download] – Download Latest Nigerian Gospel Music + Lyrics

Traffic Exchange

As requested by tons of our fans, here is Evangelist Tope Alabi’s single titled  “Mimo L’Oluwa”. Tope Alabi is undoubtedly the most sort after yoruba Gospel Minister in Nigeria.

Listen, Download and Share…


 

LYRICS:

Mimo l’Oluwa o (mimo)
Angeli nwo mike o (mimo)
Awon orun nwo mike (mimo)
Egbagbeje irawo o (mimo)
Mimo l’Oluwa (mimo)
Angeli nwo mike o (mimo)
Awon orun nwo mike (mimo)
Egbagbeje irawo o (mimo)

Agbagba merinlelogun (mimo)
N’origun merin aye o (mimo)
Ati oke, ati ile (mimo)
Seri nwo ke o (mimo)
Tani yo gori oke Oluwa (mimo)
Tabi tani yo duro ni’be o (mimo)
Eni ti o ni owo mimo (mimo)

Ati aya funfun (mimo)

Mimo l’Oluwa (mimo)
Mimo o mimo (mimo)

Mimo o mimo o mimo (mimo)
Mimo o funfun nene ni

Kabiyesi Eledumare Oba mimo (mimo)
Oba la gbogbo aye ete riba fun oba ti oda gbogbo adarihunhun
Oba ti oni emi inu eniyan pata
Oni kokoro aye l’ lowo
Adagodo emi gbogbo eniyan
Olu kogan orun ajosi edumare
Ibinigbi awuwo bi atele
Opa tiri kole o ko orun
Minimi ojo ti jeki ara odehin
Orun wawa ti o pada bo si po
Olorun ti o ‘so osupa di ale ti oun t’ oru
Oba ti ose ohun gbogbo ni asiko ni asiko

Oba ti ole fi eni ‘yi ti, ti a ole fi eyi re ti laila
Are la Oba ti eni kan obi, ti obi omo kari gbogbo aye koropodo
Olowo ori gbogbo aye pata pata ni

Oniwa funfun Oba dake se un ti enikan ole se un si
Inu ogo gangan ni oti fo owu
Ol’ ogo ti oju ogo lo ni
Ki abi o ko si
Emi o je fi o sere
Afi eni ti o ba fe gba query l’odore
Mi oje fi oju di o
Oba ti ose wo lo ju wo
Oti e leti
Aledibaje ni o

HA! CHECK ALSO:  AUDIO: Ayo Olu'Williams - Incomparable God [Lyrics + Mp3 Download] - Download Latest Nigerian Gospel Music + Lyrics

 


Download “Mimo Loluwa” Mimo-lOluwa-o-mimo.mp3 – Downloaded 0 times – 10 MB

قالب وردپرس

Comments

comments

Glorynews Online

Your Gospel Site that tells you the Gospel Happenings you need from Gh, Naija, South Africa, USA and UK. Glorynews seeks to inform the Masses of Gospel Gatherings, Happenings, and Events, with Videos, Photos and Posters with write ups from before, during and after. Whatsapp: +23376610660